Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA

Letra de 'Atewo' de Qdot - Escucha y canta en New Musicas

Varios-artistas

Nuevo Rock

Varios-artistas

Directos auronplay

Varios-artistas

Top Hits 2013

Varios-artistas

Caliente

Artist profile picture

Atewo

Qdot

Canciones

Kewu ní má fí wọlé
Kewu ní má fí wọlé ooh
Ilé ológo, ilé aláyọ'
Kewu ní má fí wọlé
Achalafuli jarafa karimu
Seribumi, serifa, seruku
Serimoka, serifa, kalisada deli ihh

Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh
(Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́)
Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh
(Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́)

Ma da faliu, ma da selifa
Senseburi molaika, ibura kanka buriji madansimo seliu
Kò oloṣo tó dí slay mama, iṣẹ ló mà ṣe
Alert mí má dún, ojú yìn ló mà ṣé
Ilé o, gbọọrọ Olùwà, lórí rẹ má ṣe'un ire
Jẹ kó mà ṣẹgàn, kó má ṣábosì
Ọmọ ológo, mà gbérà

Elohi' o, ìwọ Àdàbà
Elohi' o, ìwọ Àdàbà ah
Àdàbà tó wà nínù ọgbà, Àdàbà Mímọ' ni
Àdàbà yí o, wọlé

Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh
(Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́)
Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh
(Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́)

B'ómi ṣé wọnú àgbọn mí, kò ṣeni tó yẹ
Ọlọrun o, motelimo, sarifa tali
Mà jẹ k'àyé bù mí pé camera mí ó dà
Mà jẹ k'àyé fí mí ṣẹ̀sín pé ìwà mí ó dà
Ọlọrun Mósè, M'Orimolade Tumolaṣe
Bàbá dàmí lóhùn aiye' mí ré, bà mí túnṣe

Elohi' o, ìwọ Àdàbà
Elohi' o, ìwọ Àdàbà ah
Àdàbà tó wà nínù ọgbà, Àdàbà Mímọ' ni
Àdàbà yí o, wọlé

Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh
(Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́)
Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh
(Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́)

Ọmọ Cherubim, Seraphim
You gats to be prayerful
Torí pé, ibarasa lamalifu
Agbara luselifa
Seribumi, serifumi, elédè kewu

Ijiria falibu, saliabana kalifi
Mada selihu lona mefa
Mò pàṣẹ fowó inú afẹ'fẹ'
Kò má padà sínú afẹ'fẹ' mọ
À tí parí ẹ o

Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA